Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Okofactism (56) in agriculture • 6 years ago Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún . Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa. Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni eso cashew tuntun orí oko wa. Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 . agriculture farms homesteading nature life
Omo iya mi
Downvoting a post can decrease pending rewards and make it less visible. Common reasons:
Submit