#English
EXODUS 22:5 If anyone grazes their livestock in a field or vineyard and lets them stray and they graze in someone else’s field, the offender must make restitution from the best of their own field or vineyard.
#Yoruba
ẸKISODU 22:5 “Bí ẹnìkan bá jẹ́ kí ẹran ọ̀sìn rẹ̀ jẹ oko olóko, tabi ọgbà àjàrà ẹlòmíràn, tabi tí ó bá da ẹran wọ inú oko olóko tí wọ́n sì jẹ nǹkan ọ̀gbìn inú rẹ̀, ibi tí ó dára jùlọ ninu oko tabi ọgbà àjàrà tirẹ̀ ni yóo fi dí i fún ẹni tí ó ni oko tabi ọgbà àjàrà tí ẹran rẹ̀ jẹ.
#Hausa
EXODUS 22: 5 Idan wani ya yi kiwon dabbobinsu a gona ko gonar inabinsa, ya bar su su ɓace, su ci su a gonar wani, sai wanda ya yi laifi ya biya hakkinsa daga gonakinsa ko gonar inabinsa.
#Igbo
EXỌMỤ 22: 5 Ọ bụrụ na onye ọ bụla na-azụ anụ ụlọ ha n'ọhịa ma ọ bụ n'ubi vaịn ma na-ahapụ ha ka ha na-atagharị ma na-ata nri n'ọhịa onye ọzọ, onye ahụ mejọrọ ga-akwụghachi ya site n'ubi nke ubi ma ọ bụ ubi-vine ya.
is it true?
Downvoting a post can decrease pending rewards and make it less visible. Common reasons:
Submit